0
Yoruba proverbs
3 年前Ohun tó ṣe àkàlàmàgbò tó fi dẹkun ẹrin rínrín, tó bá ṣe igúnnugún, á wokoko mórí ẹyin ni.
Translation:
If what took laughter away from the crow had befallen the vulture, it would have been stuck brooding on its eggs.
Wisdom:
Be tolerant; different stroke for different folks.